Home ÀKỌ̀TUN Mo ti foríji Obaseki – Oshiomole
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - September 9, 2019

Mo ti foríji Obaseki – Oshiomole

Gomina ipinle Edo tele to tun je alagba patapata fun egbe oselu APC, Adams Oshiomole lo n salaye fun awon oniroyin pe ko si faa ki a jaa mo laarin oun ati gomina ipinle naa.
Oshiomole ni ife ara ilu lo fa ede aiyede oun ati gomina naa.
O ni ile-iwosan nla ti o n ko ni ipinle naa ti oun si ti san ida marundinlogorin ninu ida ogorun-un ni gomina naa fi eta inu pa ti. O ni komisona Kan ti o wa lati odo oun ni Obaseki tun le danu.
O ni bee lo n pariwo taataa pe oun ko le maa bo awon agba oloselu kankan, o ni oun ni lati gbe awon odo oloselu dide.
Oshiomole ni die lara oun to fa ede aiyede awon niyen.
Oshiomole ni oun ko beere owo bee loun ko beere ipo lati odo gomina naa.
Oshiomole ni oun tun gbaa nimoran lati maa gbe ise akanse fun awon agbasese ipinle maa.
Ju gbogbo re lo, Oshiomole ni ko sogun bee si ni ko si ote laarin awon mo. O ni nitori awon ara ipinle naa lati le je mundun-mundun eto oselu awa ara wa. O ni oun ni lati ju owo sile fun gomina naa.
Gomina Godwin Obaseki ni ko si esi fun gbogbo ohun ti Oshiomole so yii, o si kilo fun awon alabasise po re pe enikankan ko fun Oshiomole lesi.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu Ọrẹ Òtítọ́jù Olùdíje fún i…