Home ÀKỌ̀TUN Âdó olóró kankan kò dún ni ilè asojó South Africa ti Abuja – Lai Mohammed
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - September 7, 2019

Âdó olóró kankan kò dún ni ilè asojó South Africa ti Abuja – Lai Mohammed

Wahala to n sele si awon omo Naijiria to wa ni orileede South Africa ni awon oniroyin eleje ti gbe iro ķan jade si ori afefe pe, ado oloro Kan ti dun ni ile asoju orileede naa ti ko si si eni to le so ibi ti o wa.
Minisita eto iroyin ati asa ni orileede Naijiria lo tete n forere pe iro patapata ni awon oniroyin naa n pa, o ni ko si wahala kankan ni oluulu naa.
Alhaji Lai Mohammed ni fidio ti won n gbe kiri naa je ti isele ado oloro to waye ni odun 2014.
Minisita si se ikilo gidi fun awon oniroyin eleje naa ki won sora gidi ki wahala nla ma baa sele laarin orileede mejeeji.
Alagba Lai Mohammed ni ijoba ko ni fi ojuure wo awon oniroyin buruku naa ti owo ba te won.
Minisita si ro awon eniyan to wa ni ori ero ayelujara orisiirisii ki won sora nipa biba awon eniyan buruku tan iroyin eleje kaakiri.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run Ọrẹ Òtítọ́jù Ayẹyẹ ọjọ́ọ̀bì à…