Wọ́n ti ti títì Lagos-Ibadan.
Lagos State Traffic Management Authority (LASTMA) ti kede pe won ma ti lara titi Lagos-Ibadan fun atunse.
Win ti ti die lara titi naa lonii Mondey September 2, fun atunse titi di October31.
Lati agbegbe Berger titi naa ni awon osise LASTMA ati FRSC ati awon olopaa ti bere si ni dara awn eeyan si ibi ti won ma gba titi won ma fi pari atunse naa.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…