Jìgan tí jàre ikú.
Onsere onitiati Jigan Babaoja, ti jare iku leyin ti o ni ijamba oko ni ale ana, Sepetember 1.
Onsere naa gbe aworan ara re nibi ti ijamba naa ti waye, o si so pe ara n soro fun oun pe ki oun ma jade ni ana yen. O ni ijamba naa waye ni titi ijoba latati iho nla yi o wa ni titi naa.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…