Home orisiirisii Ìjàm̀bá ọkọ̀ BRT méjì ti wáyé.
orisiirisii - Orisirisi - September 2, 2019

Ìjàm̀bá ọkọ̀ BRT méjì ti wáyé.

 

Oko BRT meji ti fori gbara won ni aaro oni ni Asolo, Ikorodu ni ipinle Eko.

A ko tii mo iye awon eeyan ti won farapa, amo enikan ti isele naa soju re ni, won ti gbe gbogbo awon ti won farapa lo si ile iwosan fun itoju. Ijamba naa waye ni ibi ti oko BRT ma n duro si, o si ti fa sukere fakere oko ni titi naa.

Ijamba naa waye leyin bi i ose kan ti ijamba waye laaari BRT kan ati tirela, ti awon eeyan si farapa ni agbegbe Ikorodu ni ipinle Eko.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…