Home orisiirisii Gómìnà Kayode Fayemi n ṣe ayẹyẹ ìgbéyàwó.
orisiirisii - Orisirisi - September 2, 2019

Gómìnà Kayode Fayemi n ṣe ayẹyẹ ìgbéyàwó.

 

Gomina ipinle Ekiti, Kayode Fayemi ati iyawo re, Labisi n se ayeye igbeyawo olodun ogbon.

Gomina naa gbe aworan oun ati iyawo si afefelati se ayeye igbeyawo naa. O ni ‘Labisi, ogbon odun a si tun n lo. O se pe o je iyawo dada, enikeji rere, iya rere si Oluwafolajimi ati ore mi timo timo ni gbogbo igba. Ku ayeye igbeyawo. JKF si wura ti o ni iye re ni ayeye igbeyawo ogbon odun won.’

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…