Home orisiirisii Bukola Saraki ti lọ wo eré ìdárayá.
orisiirisii - Orisirisi - September 2, 2019

Bukola Saraki ti lọ wo eré ìdárayá.

 

Aare senati ana, Bukoka Sarakiati awon omo re okunrin meji ti lo wo ere idaraya Arsenal ati Tottenham ni stadium Emirates.

O gbe aworan oun ti awon omo re si ori afefe, o si ni’ a sese de Emirates stafiu, lati se o NLD(Arsenal vs Tottenham) pelu awon omo mi, Seni ati Niyi. O dara lara l a ti wo ere idaraya orogun meji pelu awon molebi mi.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…