Home orisiirisii Bàbá ti dáná sun ọmọ rẹ̀.
orisiirisii - Orisirisi - September 2, 2019

Bàbá ti dáná sun ọmọ rẹ̀.

 

Omokunrin kekere kan ti n je Abasiofon Idorenyin n ja fun emi re lowo lowo ni ile iwosan, leyin ti baba re da epo lu u ti o si dana sun un.

A gbo isele naa waye ni Afia Nsit ni Eket LGA ni ipinle Akwa Ibom ni ojo Thursday August 29, leyin ti arakunrin kan ti n je Ogbeni. Idoreyin fi esun kan omo naa pe o ji 500naira lodo onile won.

Orisirisi ni o n sele bayii, ki olorun ba wa ba esu wi.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…