Home orisiirisii Àwọn ọlọ́pàá ti mu olè.
orisiirisii - Orisirisi - September 2, 2019

Àwọn ọlọ́pàá ti mu olè.

 

Awon olopaa ipinle Eko ti mu arakunrin kan ti n je Wasiu Kamarudeen, omo odun mokandinlogun, fun esun pe oun ati awon meji kan lo ja awon eeyan lole ni Jakande open field, nibi ti ile ijosin St Patrick Catholic Renewal Church ti n je isin olojo meta.

Won ba ibon ibile ati ota lọ́wọ́ arákùnrin naa ti n gbe ni No. 8 Olaniyi Street ni Iyalode Ilogno ni Badagry, ipinle Eko. Awon ara ile ijosin naa ni won kepe awon olopaa niba ti won ri okada ajeje pelu eeyan meta lori re ti o mu ifura dani ti o si wole to won wa.

Agbenuso olopaa ipinle Eko, DSP Bala Elkana, ni awon okunrin naa darapo mo awon ara ijosin naa lati ba won josin pelu ero pe won ma ja won lole. O ni won ti yan awon SARS lati wa awon meji ti o ku.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…