Home orisiirisii Arábìnrin ti ta ọmọ.
orisiirisii - Orisirisi - September 2, 2019

Arábìnrin ti ta ọmọ.

 

Awon olopaa ipinle Niger ti gbe arabinrin kan ti n je Bose Isaac fun esun pe o ta omo ti o ji gbe fun 30,000naira.

Won ni arabinrin naa ti n gbiyanju ati salo, nigba ti enikan ti o je baba omo naa, Gambo Shua’ibu wa fi ejò sun ago olopaa pe oun wa omo oun ni ilu Cikin-Gari ni August 24.

Agbenuso awon olopaa ipinle Niger, Muhammad Abubakar ni awon olopaa Kagara Division ni won mu arabinrin naa. Gege bi o se sp, Bose Isaac ti jewo pe oun ji omo naa gbe, oun si fe lo ta a fun arabinrin kan ni ipimle Ogun fun 30,000naira.

Arabinrin naa ti o ni oun nilo owo lati yanju isoro molebi, ni eni ti o fe ra omo naa o tii san eje tire.

Muhammad ti so pe awon olopaa ti n sa gbogbo ipa won lati mu arabinrin ti o fe ra omo naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…