Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni odo re ni agbegbe Ishasi ni ipinle Eko.
Enikan ti n je @_ejembi lori Instagram, lo pe akiyesi olopaa @Opetodolapo ati awon naa kan si isele naa.
Arabinrin ti won ni mummy Onyi ti n gbe ni Iyana Ishasi ni ipinle Eko, da omi gbona si oju ara omo naa, o si de e mole lati toju re ki awon eeyan ma ba ri ise ibi naa.
Won ti gba omo naa sile, o si ti n gba itoju lowo ni ile iwosan. Owo olopaa ti te arabirin naa ti o ti n sa pamo kiri ni aaro oni.
Bàbá ti dáná sun ọmọ rẹ̀.
Omokunrin kekere kan ti n je Abasiofon Idorenyin n ja fun emi re lowo lowo ni ile i…