Wọ́n ti ṣá arákùnrin pa.
Awon apaniyan ti sa olokada kan ti n je Sunday Olorunleke pa ni ojo Satide, August 31 ni ile re ni agbegbe Aba ni Ado Ekiti ni ipinle Ekiti.
A gbo pe arakunrin naa ti o ni omo meji nikan lo wa ni ile nigba ti awon apaniyan naa lo si inu re ti won si sa pa si ibe.
Iroyinni iyawo re ati awon re ti won rin irin ajo kuro ni Ado Ekiti ni ojo Wednesday, de ni aaro ojo Satide, won si ba oku re nile.
PRO awon olopaa ipinle naa, Caleb Ikechukwu, lo fi idi eri isele naa mule, o si ni iwadii ti n lo lori isele naa.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…