Home orisiirisii Arákùnrin ti pa ara rẹ̀.
orisiirisii - Orisirisi - September 1, 2019

Arákùnrin ti pa ara rẹ̀.

 

Arákùnrin kan ti n je Seyi Onayemi, omo odun metadinlogoji ti gba emi ara re ni agbegbe Ikorodu ni ipinle Eko ji ojo Friday August 30.

Agbenuso awon olopaa ipinle Eko, Bala Elkana, so pe ni ojo Friday August 30 ni awon olopaa oga olopaa ti Shagamu gba ipe ijaya pe arakunrin naa mu nkankan ti won lero pe o je oogun p’efon (Sniper), o si ku si inu yara re ni 7th Avenue, Rofo Estate, Odongunyan, ni titi Shagamu, Ikorodu.

Bala ni awon ti won ma n se iwadii iru isele naa lo si ibi ti isele naa ti waye, won si ti gbe oku naa lo si mosuari.

Won ri ike oogun p’efon naa, ati iwe ti o ko sile nibi yi isele naa ti waye.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…