Home orisiirisii Pásítọ̀ ti wo wèrè sàn.
orisiirisii - Orisirisi - August 31, 2019

Pásítọ̀ ti wo wèrè sàn.

 

Ero ti pejo si Choba junction n ipinle Port Harcourt leyin ti won ni pasito wo were san.

Ninu fideo ti won gbe si ori afefe, pasito naa fi tesbili awon catholic si orun, o si lo ba were naa.

Nigba ti o se die, ero pejo po leyin ti ara were naa san, pasito naa si fa gnogno irun ori re, ki o le see ri.

Ninu fidio naa, awon eeyan n f I esun kan arakunrin naa pe igbo ti o ma n fa lo fa ara opolo naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…