Home orisiirisii Ọlọ́pàá ti fi obìnrin sí ẹ̀wọ̀n.
orisiirisii - Orisirisi - August 31, 2019

Ọlọ́pàá ti fi obìnrin sí ẹ̀wọ̀n.

 

Arabinrin ti ke pe awon eeyan lori instagram,ti o fi si fi esun kan olopaa kan pe o fi aburo oun obinrin si ewon nitori ko ki olopaa naa.

@_royaltiegram gbe fideo ai ori instagram, o si ni olopaa ti o wa ni eyin oburo re ni o n je Ogbeni Eric ti Area F ni Ikeja ni ipinle Eko. O fi esun kan awon olopaa Area F pe won ma n fi ipa ba awon eeyan lopo, won si ma n pa eeyan.

Arabinrin naa ni olopaa naa so pe ki oun san egberun márùn-ún ki oun to fi aburo re sile. Amo arabinrin naa oje ki a mo boya won san owo naa abi won o san an.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…