Ẹ kó owó tí kò dára lọ sí báǹkì – CBN.
Central Bank of Nigeria (CBN) ti so fun awon omo Nigerja pe ki won ko gbogno owo ti ko ba dara mo lo si ile ifowopamo ki o to di ojo Monday, September 2.
CBN ni idi ti won fi so eyi ni lati paro awon owo ti ko darati awon eeyan n na. Awon owo ti won fe ki awon eeyan ko wa ni owo ti o ti re ti o si le ya ti won ba lo na, owo ti o ta ya, amo ti won si le ri ju idaji lara owo naa.
Won se ipolongo naa ninu iranse ti GTBank ranse si awon onibara won ni ojo Friday, August 30.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…