Home orisiirisii Àgbàlagbà ti fi ipá bá ọmọ ọdún méjì lòpọ̀.
orisiirisii - Orisirisi - August 31, 2019

Àgbàlagbà ti fi ipá bá ọmọ ọdún méjì lòpọ̀.

 

 

Awon olopaa ipinle Abia ti gbe arakunrin omo odun ogoji leyin ti won fi esun kan an pe o fi ioa ba omo odun meji lopo.

Ajafetoo,Harrison Gwamnishu, lo gbe isele naa si ori afefe, o ni mama omo naa Ihechi Ndubuisi, ma n ta akara ni iwaju estate ti arakunrin naa ti n se ise oludaabo. Ni August 22, o tan omo naa si ibi ise re, o si fi ipa ba lopo, mama omo naa ba omo re nile pelu eje ni gbogbo ara re.

Won ti mu arakunrin naa, o si wa ni Area Command Isiukwuato, ni ipinle Abia.

Omo naa si wa ni ile iwosan ni ibi ti o ti n gbe itoju. Won ni arakunrin naa yoo to fi oju ba ile

 

 

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…