Home orisiirisii Wọ́n ti yin ìbọn pa arákùnrin.
orisiirisii - Orisirisi - August 30, 2019

Wọ́n ti yin ìbọn pa arákùnrin.

 

Won ti yin ibon pa arakunrin omo odun mejidinlaadota ti n je Johnson Taiga, ni Edjophe community, ni Ugheli South ni ipinle Delta ni ojo Tuesday.

Oloogbe na je egbon Alaga Defence of Human Rights(CDHR) ti ipinle Delta ti n je, Omo oba Kehinde Taiga. O fe lo ki ore re ti n je Asatweh nigba ti awon okunrin mejo kan bere si ni yin ibon ni adugbo naa lati deruba awon eeyan. Nigba ti o ya ni won dojuko oloogbe naa, won yin ibon fun, won si sha ni ada.

Oburo oloogbe naa ti o je alaga CDHR, ti kero nipa isele naa, o si ti soro nipa awon iwa buruku ti awon omo egbe okunkun naa n wu ni agbegbe Udu ati Ugheli ni ipinle naa. O ti ke pe awon oludaabo paapaa awon olopaa pe ki won fi ise kun ise won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…