Home orisiirisii Wọ́n ti jí olóṣèlú gbé.
orisiirisii - Orisirisi - August 30, 2019

Wọ́n ti jí olóṣèlú gbé.

 

Won ti ji okan lara awon osise House of Assembly ipinle Kaduna ni titi Kaduna-Zaria ni oni August 30.

Agbenuso awon olopaa ipinle Kaduna, YakubuSabo, lo fi idi eri isele naa mule, o si ni awon olopaa ti wa ninu igbo naa lati ri pe won ri arakunrin naa mu lo si ile ni ayo ati alaafia.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…