Home orisiirisii Wọ́n ti dáná sún àlùfáà Kátólíìkì.
orisiirisii - Orisirisi - August 30, 2019

Wọ́n ti dáná sún àlùfáà Kátólíìkì.

 

Won ti dana sun alufaa katolikiiti o rin irin ajo nipa alaafia niipinke Taraba.

Won yin ibon pa Reverend Father David Tanko, ni Kufai Amadu ni ipinle Taraba.

Alufaa naa n lo di Takum fun ipade nipa alaafia, oun ati alufaa egbe reni won je lo lati yanju wahala Tiv ati Junk nigba ti won pa w.

Alaga kabsu naa, Shiban Tikari, so pe leyin ti won pa a, won dana sun oun ati oko re. O si fi esun kan awon ologun Tiv pe awon ni won se ise naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…