Wọ́n ti ṣe ìsìnkú Àgùnbánirọ̀
Won ti se isinku okan ninu awon agunbaniro ti o ku si inu ijamba oko nigba ti oun ati awon agunbaniro omo ijo catholic n rin irin ajo.
Jacinta Chinenye Ndem wa ninh oko ti o je ti National Association of Catholic Corps members (NACC) nigba ti won ni ijamba oko ni ojo Sunday, August 18, ti o si padanu emi re.
Won sin omo odun merinlelogun naa ni ojo Thursday, August 29, ni ilu re ni Afikpo, ipinle Ebonyi.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…