Home orisiirisii Hafiz Oyetoro ti pàdánù màmá rẹ̀.
orisiirisii - Orisirisi - August 30, 2019

Hafiz Oyetoro ti pàdánù màmá rẹ̀.

 

Gbajumo onsere, Hafiz Oyetoro ti awon eeyan mo si Saka ti padanu mama re.

Saka padanu mama re ni ana August 29. Mama naa je omo doun mejilelaadorun, won si ti sin oku naa gege bi asa musulumi.

Onsere naa sukun nibi isinku naa, o si ti je ki od i mimo pe oun ti di omo oru kan.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…