DjCuppy ti lọ kí àwọn ọmọ ti ìjà Borno pa lára.
Omo onisowo bilionu,Femi Otedola,DJ Cuppy ti n je Florence Ifeoluwa Otedola, ti lo ki awon omo ti ijamba Borno pa lara ni Save the Children Stabilization Centre ni Maiduguri ni ipinle Borno.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…