Home Entertainment Àwòrán Toyin Abraham àti ọmọ rẹ̀.
Entertainment - orisiirisii - Orisirisi - August 30, 2019

Àwòrán Toyin Abraham àti ọmọ rẹ̀.

 

Toyin Abraham ti gbe aworan oun ati omo re, Ire, si ori instagram lonii ojo Friday, August 30.

Toyin ati baba omo re Kolawole Ajeyemi bi omo won ni ose meji seyin.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…