Home orisiirisii Wọ́n ti yin ìbọn pa akẹ́kọ̀ọ́.
orisiirisii - Orisirisi - August 29, 2019

Wọ́n ti yin ìbọn pa akẹ́kọ̀ọ́.

 

Won ti yin ibon pa akekoo okunrin ti o n je Ajayi Samuel ti awon eeyan mo si “Preacher” ni odun kerin ni eka onisiro ni ile iwe Federal College of Education (Technical), Akoka ni ioinoe Eko. Won ni awon omo egbe okunkun ni won yin ibon naa.

Gege bi iroyin se so, awon omo egbe okunkun kan wa si ile iwe naa nigba ti won n ko idanwo ti o gbeyin, won si Samuel ti o je omo awon obi re kan soso lo si ile ounje kan lati lo jeun. Bi o se fe jade lati ike ounje naa ni won yin ibon fun ni oorun ti o si ku lesekese.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…