Wọ́n ti mú olè.
Wọ́n ti mú olè.
Won ti mu arabinrin kan ti o jale ni ile awon omo alaini iya kan ni ipinle Anambra. Won fi agadangodo da owo re, won si n mu kaakiri. Won ni o ji awon ounje ati orisirisi nnkan miiran ti o je ti awon omo naa.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…