Home orisiirisii Wọ́n ti gba ìwé ìwọ̀lú lọ́wọ́ Biodun Fatoyinbo.
orisiirisii - Orisirisi - August 29, 2019

Wọ́n ti gba ìwé ìwọ̀lú lọ́wọ́ Biodun Fatoyinbo.

 

Awon ti won n se iforowanilenwo fun Biocun Fatoyinbo Force Criminal Investigation Department(FCID) ni Abuja, ti lo tu ile re ati ofisi re ni ni ana ojo Wednesday,August 28.

Gege bi iroyin Daily Sun, won ni awon olopaa ti gba iwe iwolu(international passport) Fatoyinbo, gege bi ara baali ti won fun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…