Home iroyin Wọ́n ti pa ọmọ Nigeria ni South Africa.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - August 28, 2019

Wọ́n ti pa ọmọ Nigeria ni South Africa.

 

Won ti pa arakunrinomo Nigeria omo odun merindinlaadota ti n je Pius Ezekwem, ti n gbe ni Easthern Cape ni orile-ede South Africa.

Gege bi iroyin se so, Pius ti o ni ile itura ti o fi n sise,ni awon olopaa mejo gbe nibi ti o ti n jeun ni ile ounje ti Nigeria ni opin ose ti o koja, won si fi ipa mu lo si ile re lati lo tu.

Ariyanjiyan waye laaarin Puus ati awon olopaa naa, ti o fa a ti won yin inon fun, ti o fa iku re. Iyawo oloogbe naa ti o je omo South Africa wa ni ibi isele naa. Won ni oloogba naa so fun awon olopaa naa pe ki won pa oun si ile oun pe oun o ni tele won lo si ago olopaa, won si yin ibon pa a.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…