Home orisiirisii Wọ́n ti mú akẹ́kọ̀ọ́ tí o fe pa ara rẹ̀.
orisiirisii - Orisirisi - August 28, 2019

Wọ́n ti mú akẹ́kọ̀ọ́ tí o fe pa ara rẹ̀.

 

Ile ejo kan ni Minaa ti pase ki won fi akekoo omo odun mokadinlogun, ti n je Suleiman Ayuba si ewon titi won ma fi dajo fun, leyin ti o gbiyanju ati pa ara re.

Adajo Hauwa Yusuf, lo pa ase naa leyin ti Ayuba ni oun jebi, o si ti ni won ma dajo re ni September 16. Won fi esun igbiyanju ati paniyan kan Ayuba, gege bi ofin se so ni Section 231 ti Penal Code Law of Niger State.

Nigba ti won bere idi ti o se fe pa ara re, o ni “o ni oun fe pa ara oun nitori aye ti le ju fun oun bi oun se je omo oru kan.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…