Home orisiirisii Tẹ́náǹtì ti pa onílé rẹ̀.
orisiirisii - Orisirisi - August 28, 2019

Tẹ́náǹtì ti pa onílé rẹ̀.

 

Awon olopaa ipinle Ekiti ti gbe arakunrin omo odun mokandinlogoji kan ti n je Tunmise Abraham, fun esun pe o fi ipa ba onile re ti n je Mrs Bukola Olaranrewaju lopo, o si pa a ni Ado Ekiti.

Arakunrin naa ni oun fi igi gba Mrs Bukola, ti o je omo odun mejidinlogbon, ti o si ti bi omo meta, pelu ibinu, amo oun o mo on mo pa a. O fi esun kan oloogbe naa pe o ma n bu oun nitori ma n kalolo, o si ma n pe oun ni were.

Nigba ti won gba lo si Headawon olopaa ipinle naa, komisona olopaa ipinle naa, Mr Amba Asuquo, ni won mu arakunrin naa ni Akure nibi ti o lo sa pamo si leyin ti o pa arabinrin naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…