Home orisiirisii Ọmọ Nigeria ti gba ọkùnrin tí ó yára ju ní Africa.
orisiirisii - Orisirisi - August 28, 2019

Ọmọ Nigeria ti gba ọkùnrin tí ó yára ju ní Africa.

 

Omo Nigeria ti n je Raymond Ekevwo ti gba ipo okunrin ti o yara sare ju ni Africa leyin ti o sare ni aarin 9.96secs ni ayeye 100m ti n lo ni 2019 African Games.

Omo Nigeria miiran kan ti n je Usheori Itsekiri, ni o gbe ipo keta laarin10.2secs ni ayeye naa ni Morocco.

Igba akoko ti Nugeria ma gba ipo kinni ni 100m race ti okunrin ni African Games lati 2007.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…