Home orisiirisii Ọkọ̀ méjì ti kọlu ra wọn.
orisiirisii - Orisirisi - August 28, 2019

Ọkọ̀ méjì ti kọlu ra wọn.

 

Ibi ti re ni irole ana ni Auchi ni ipinle Edo, leyin ti oko Dangote ati oko God is God kolu ara won.

Okan lara awon ti n rin ajo lati Port Harcourt lo si Abuja, ni emi kankan o bo si ijamba naa.

Isele naa waye leyin wakati die ti oko Dangote kolu BRT ti n na Ikorodu ni ipinle Eko.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…