Home orisiirisii Biodun Fatoyinbo sì wà ní ọ̀dọ̀ àwọn ọlọ́pàá.
orisiirisii - Orisirisi - August 28, 2019

Biodun Fatoyinbo sì wà ní ọ̀dọ̀ àwọn ọlọ́pàá.

 

Pasito Commonwealth of Zion Assembly COZ, Biodun Fatoyinbo, si wa ni odo awon olopaa leyin wakati mejo ti o ti wa lodo won ni ojo Tuesday August 27, lodo awon Force Criminal Investigation ti Abuja, fun esun ifipabalopo ti iyawo Timi Dakolo, Busola Dakolo fi kan an.

Won fun Fatoyinbo ni beili ni ago mesan, amo o si wa ni odo won nitori ko tii san beili naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…