Home orisiirisii Wọ́n ti pa ọmọ Nigeria ni South Africa.
orisiirisii - Orisirisi - August 27, 2019

Wọ́n ti pa ọmọ Nigeria ni South Africa.

Won ma sin Benjamin Okoronkwo, omo odun metaleligoji ti n wa oko, ni ono Fruday, August 30 ni ile awon molebi re ni Okposi, Ohaozara local government ni ipinle Ebonyi.

Awon apaniyan ni won yin ibin pa Okoronkwo ni ago meta oru ni orile ede South Africa.

O fi awon omo meji, pelu iyawo re ti o wa ninu oyun sile si aye.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…