Home iroyin Wọ́n ti fi owó kún owó físà America.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - August 27, 2019

Wọ́n ti fi owó kún owó físà America.

 

Embassy orile ede America ni Nigeria ti so pe lati ojo Thursday, August 29 odun yii, awon omo Nigeria ti o ba fe gba fisa a ma a san $110(40,700) lati gba fisa won ti won ba fun won. Eyi yato si owo fisa 59,200 naira ti won n gba.

Won ni idi ti won se fi owo kun owo fisa naa ni pe, won ma n ni ki aaon omo America san owo ribiribi lati gba fisa Nigeria ni Embassy Nigeria ti o wa ni America.

Won ni won gbiyanju lati ba ijoba soro ki won din owo naa ku, amo won o gba. Eyi lo faa ti awon naa se fi owo kun owo fisa awon.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…