Home orisiirisii Biodun Fatoyinbo ti lo fún ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò lọ́dọ̀ àwọn ọlọ́pàá.
orisiirisii - Orisirisi - August 27, 2019

Biodun Fatoyinbo ti lo fún ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò lọ́dọ̀ àwọn ọlọ́pàá.

 

Biodun Fatoyinbo, Pasito Commonwealth of Zion Assembly (COZA) ti fi ara re sile fun awon olopaa, won si ti n bere oro lowo re ni Police Force CID Headquarters ni Abuja fun esun ifipabalopo ti iyawo Timi Dakolo,Busola Dakolo fi kan an.

Egbe eleyan merinti igbakeji komisona olopaa, Uche Anyan dari re ni o n bere oro lowo re.

Won n reyi ki Fatoyinbo pe ni ibe nitori ifoworowanilenuwo awon Dakolo to wakati mejo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…