Home Entertainment Àwòrán lati ìkómọ ọmọ Ronke Odusanya.
Entertainment - orisiirisii - Orisirisi - August 27, 2019

Àwòrán lati ìkómọ ọmọ Ronke Odusanya.

 

Ni bi ose kan seyin ni gbajumo osere Ronke Odusanya bi omo re akoko ni orile ede America, won si ti se ikomo omo naa gege bi esin musulumi ni opin oseti o koja.

Onsere naa ati baba omo re,Saheed Aranmolate ti awon eeyan mo si Don Jago so omo won ni Oluwafifehanmi,Fareeha, Olamiposi.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…