Home orisiirisii Arábìnrin ti pa ọkọ rẹ̀.
orisiirisii - Orisirisi - August 27, 2019

Arábìnrin ti pa ọkọ rẹ̀.

 

Awon olopaa ipinle Kebbi ti mu arabinrin kan ti n je Auta Dogo Singe fun esun pe o pa oko re ti n je Shaho Abdullahi ni Bagudo local government area ni ipinle Kebbi, o pa oko re ki o le pada si odo oko re aaro, Idris Garba.

Komisona ipinle Kebbi, Garba Muhammed Danjuma, lo fi idi eri isele naa mule, o ni arabinrin naa pawopo pelu Garba Hassan ati Sahabi Garba kan ni ilu Sabon Gari, ni agbegbe Illo ni Bagudo lati pa Shaho ki o le fe Garba.

O ni won ti mu arabinrin naa ati awon okunrin mejeeji, pe won a to fi oju ba ile ejo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…