Home iroyin Wọ́n ti mú àwọn ẹlẹ́gbẹ́ òkùnkùn.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - August 26, 2019

Wọ́n ti mú àwọn ẹlẹ́gbẹ́ òkùnkùn.

 

Awon osise Operation Crush lati eka Anti-Cultism ti mu awon marundinlogbon ti won fura si pe won je elegbe okunkun ni agbegbe Ijora, Mushin ati Bariga ni ipinle Eko laaarin ojo kan.

Agbenuso olopaa ipinle Eko, Bala Elkana, ti fihan ninu gbolohun ti o fi kale pe ason oludaabo mu Olaitan Rilwan kan ni ojo Satide ni roundabout ti ijora.

O ni omo ogun odun naa ti ka pe omo egbe okunkun Aiye ni oun, won si ba ibon ninu apamowo re. Nigba ti won se iwadii ni Bariga ni won mu omo odun metalelogun Mustapha Oseni ati awon mejilelogun.

O ni won ba ibon ibile kan agi ota mejo lowo re. O ni gbogbo awon ti won fura si naa ma to fi oju ba ile ejo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…