Home orisiirisii Ọkọ àti ìyàwó ti fi ìyà jẹ ọmọ ọ̀dọ̀ wọn.
orisiirisii - Orisirisi - August 26, 2019

Ọkọ àti ìyàwó ti fi ìyà jẹ ọmọ ọ̀dọ̀ wọn.

 

Oko ati iyawo kan ni Nnewi ti n dokuko ibawi leyin ti won fi iya je ọmọbìnrin kekere kan ti n se omo odo lodo won.

Kelvin Ugochi lo gbe isele naa si ori Facebook, o ni ana ni oun ri omo naa August 25 ni ile epo ti eru si n ba omo naa.

O ni leyin ti oun bere oro lowo omo naa, o ni awon ti oun n ba gbe ni won gi iya je oun. Kelvin ni oun mu omo naa lo si ile, pe nigba ti oun de ibe, awon ti o n ba gbe naa ni iya ti o je ko tii to rara.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…