Home Entertainment Davido ti ra ọkọ̀ tuntun.
Entertainment - orisiirisii - Orisirisi - August 26, 2019

Davido ti ra ọkọ̀ tuntun.

 

Eyi waye leyin bi ojo meji seyin ti gbajumo akorin naa so pe oun o tii wa ikokan ninu awon oko oun ni odun yii.

O si ti gbe aworan oko tuntun olowo nla Lamboghini ti o sese ra si ori instagram.

O ku oriire.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…