Àwòrán Genevieve Nnaji.
Gbajumo onsere onitiata, Genevieve Nnaji gbe aworan ara re ti o rewa yii si ori afefe. Onsere naa je omo ogoji odun amo, afi bi omo ogun odun ni o se ri.
O dara ki obinrin maa toju ara re.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…