Home orisiirisii Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ti fárígá.
orisiirisii - Orisirisi - August 26, 2019

Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ti fárígá.

 

Awon akekoo ile iwe Yunifasiti ti ipinle Benue ti faragi won ti fi ehonu han ni aaro oni ojo Monday, leyin ti lero fun si awin omo egbe okunku pe won yin ibon fun Aare National Union of Benue State Studnet(NUBESS) Comr. Tyonor Smith ni ale ojo Sunday.

Won yin ibon fun aare naa ni iwaju geeti Benue State University College of Health Scienece ni nnkan bi ago mejo koja iseju merinlelogbon ale nigba ti o n bota ni ile iwe. Won sare gbe lo si ile iwosan fun itoju.

Agbenuso olopaa ipinle Benue, DSP Catherine Anene, lo fi idi eri isele naa mule, o ni iwadii fihan pe Smith si oro oselu ile iwe naa, a ti oe ibo n bo lona, pe awon ti won jo n du ipo ni o se e se ki won wu iwa naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…