Home orisiirisii Akẹ́kọ̀ọ́ ti pàdánù ẹ̀mí rè.
orisiirisii - Orisirisi - August 26, 2019

Akẹ́kọ̀ọ́ ti pàdánù ẹ̀mí rè.

 

Akekoo okunrin ni eka ofin ni ile iwe Lagos State University ti padanu emi re nibi ti o tin ka iwe.

Won ri oku akekoo naa ti n je Hillary ni aaro oni ni yara ikawe ti ika ofin.

Gege awon elegbe re se so, won ni o se e se ki o je akaju iwe tabi aloju caffiene, awon nnkan ti ko ni je ki eeyan sun lo fa iku naa.

V.C ile iwe naa ti pase pe ki won ti yara ikawe naa pa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…