Home orisiirisii Akẹ́kọ̀ọ́ ti fi ojú olóore gún igi.
orisiirisii - Orisirisi - August 26, 2019

Akẹ́kọ̀ọ́ ti fi ojú olóore gún igi.

 

Akekoo obinrin kan ti n je Bukola ni ile iwe Tai Solarin University of Education ni ipinle Ogun, ti da omi gbona lu ore re leyin ariyanjiyan ranpe ti won ni.

A gbo pe isele naa waye ni aaro ojo Satide nigba ti Busola ti o je eni ti won da omi gbona si lara n sun.

Odo Busola ni Bukola n gbe nitiro ko ni owo ti o le fi gba tie. Ni aaro ojo Satide ni won jo ni gbolohun aso naa.

Leyin ti won ba won yanju oro naa, Busola lo sun lai mo pe Bukola ti lo gbe omi ti o ma da luu lena.

Omi gbona yii lo ji Busola lati oju orun, gege bi alaanu ti o je, o ti ni ki won dariji Bukola.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…