Home orisiirisii Toyin Abraham ti ṣe ìkómọ ọmọ rẹ̀.
orisiirisii - Orisirisi - August 25, 2019

Toyin Abraham ti ṣe ìkómọ ọmọ rẹ̀.

 

Won ti se ayeye metalokan fun Toyin Abraham ati ikomo omo re ni ana ni ipinle Eko.

Onsere egbe re, Nkechi Blessing ni o se eto ayeye naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…