Home orisiirisii Arábìnrin ti ta ọmọ rẹ̀.
orisiirisii - Orisirisi - August 25, 2019

Arábìnrin ti ta ọmọ rẹ̀.

 

Awon olopaa ipinle Imo ti mu arabinrin kan ti n je Chinasa Ukaonu fun esun pe o ta omo re fun 500,000 naira leyin ti o bi.

O ti da ogbon ati ta omo naa ki o to so fun oko re PromiseUkaonu pe oun lo si odo egbon ounni Mbaitoli nigba yi oyun naa wa ni osun kejo. Leyin ti o paro fun oko repe oun ti padanu oyun naa ni o lo si ibi ti won ti n ta omo ti awon noosi meji kan, Esomonu Dorothy ati Eke Catherine se gbebi oyun naa.

Nigba ti Promise fura ni o fi ejo sun awon olopaa ti won si gbe Chinasa, o si jewo oruko awon ti won gbebi re ati oruko eni ti o ta omo naa fun ti n je Chioma Amadi.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…