Home orisiirisii Wọ́n ti rí òkú arábìnrin lórí àkìtàn.
orisiirisii - Orisirisi - August 23, 2019

Wọ́n ti rí òkú arábìnrin lórí àkìtàn.

 

Won ti ri oku arabinrin kan ti n jera ni ori akitan kan ni Aggrey road, Port Harcourt ni ipinle Rivers.

Gege bi eni ti isele naa soju re se so, o ni ni ojo Sunday ti o koja ni won ti bere si n wa arabinrin naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…