Home orisiirisii Wọ́n ti mú àwọn apànìyàn méjì.
orisiirisii - Orisirisi - August 23, 2019

Wọ́n ti mú àwọn apànìyàn méjì.

 

Awon olopaa ipinle Ogun ti mu awon arakunrin meji ti won fi esun kan pe won pa arakunrin olokoda kan won si ji okada re.

Agbenuso awon olopaa ipinke naa, DSP Abimbola Oyeyemi, lo fi idi eri isele naa mule, awon arakunrin naa, Lekan Odusote ati Mobday Molipa, tan olokada naa lo si agbegbe Ikangba, ni Obalende ni Ijebu-Ode, nibi ti won pa a si ti won gbe iho gi won si sin si.

Won gbe okada re, won si ta fun N120,000. Nigba ti won o le pin owo naa ni tunbinubi ni won gbe oro naa lo si odo olopaa.

Nigba ti won gbonoro naa ni DPO ti Obalande, CSP Sunday Omonijo ni ki won gbe won.

Nigba ti won bere ejo lowo won, wonnka pe awon tan lo si ibikan, awon paa, awon si gbe okada re ti awon ta, pinpin owo okada naa lo si da ija sile.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…