Funke Akindele-Bello ń ṣe ayẹyẹ ọdún ìgbéyàwó.
Funke Akindele ati oko re JJC Skillz n se ayeye odun igbeyawo olodun keta lonii August 23. Funke si gbe orisirisi aworan oun ati oko re si ori instagram lati se ayeye naa
O ni”A fi ogo fun oluwa! Ololufemi mi, Oba mi! Mo ma nife re titi lai lai.#akuayeyeodunigbeyawo#
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…